27/07/2025
I Thank Almighty Allah for today of my special day πππππππππππππ
πΏπΏπΏπΏπΏALHAMDULLILAH πΏπΏπΏπΏπΏ
Congratulations, and Happy birthday to me
ABIDAS OYO
May God continue to shower me with blessings and happiness. May He always keep mine in his tender and loving care.
ππΌAamen πΏππΎ
Adisa Omo Abidogun,
Ajadi molaba, laibade mola oke mesun agbo, Aki je mesun agbo,ki ma ni agbo funfun nile,
Omo a gbolu, to so ilu Oyo dero, laibade omo Abidogun,
Ose okunrin bawon niso Loja Akesan, iso Ajadi nbe Loja gbinrin lodan, Aniso Loja Masan owo fun ijoba
Omo omusu laja obinrin, fi gun iyanje
Omo soki o odo tanan, kini ijokeji kikan lokan
Omo a bi ode nla gbaragada bi ode adula,
Omo ajilalaeso, afijo gbogbo dara bi egbin
Tiko basi ileke,tikosi owu, tiko a*o
Orisrisi idi laba, mari,bi kokoo, bi egbon
Oniwanu bora sile, oriwalamiwami
Omo abidogun ,ti agunbiade joko ti
Ti Jabata nso loju,ti won ni ohun kohun, ko gbodo mu
Omo laibade ooooo,Ero sese lafin oba
Obebe be ara Oyo oooo,Ero sese lafin oba
Abidas Oyo II